Smiley face

Aye Ye Yinka Adonai Ni Ilu Ibadan


Eniyan ko ni taja erupe ko ma gbowo okuta laila. Aye ye Yinka Adonai lopin ose yii nibi ifilole awo orin re tuntun to pe akole re ni LAW OF KARMA. Ilu Ibadan, ilu Ogunmola ni ifilole naa ti waye gbogbo olorin ilu Ibadan ati leyin odi ni won si dide lati se aponle Yinka . Yinka Ayefele naa wa nibi ifilole orin naa ati awon agba olorin mii.


 
Adonai ti ranse ikinni si gbogbo awon ololufe re ti won dide wa sibi ifilole naa to waye lopin ose to koja. Ohun ti omokunrin olorin naa so ni yii :
Its with all pleasure and grateful heart I am saying a HUGE Thank You for attending the album launch of Yinka James&Adonai Band. Indeed you're my person and you really made my day. May God in His infinite mercy bless you and grant you all your heart desires. Thanks!!!
Orin tuntun ni Law of Karma eleyii to kun fun ogbon, e gbiyanju ke e ra ti yin lonii. ire
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment