Asa awon omo olorin ilu Amerika ni awon omobirin olorin
Nigeria naa n tele bayii. Ara won ni won fi n gbe ise won laruge. Lara
awon omo olorin ile Amerika ti won wo awokose won ni Nicki Minaj je pelu
bo se maa n fi ibadi re 'deruba' gbogbo aye.
Sugbon ka
maa paro, eru ti omo naa n gbe sunle ko dara rara. Ki ibadi omoge ri
yakata bi idi pepeye, ko tun wa ki sara bi ijoko masiini olokada bajad.
E
woo, nnkan ju nnkan lo. Ibadi Nicki Minaj ni yii, o si wa lara nnkan to
fi n polowo ise orin re. Nitori iwadii fi han wi pe opolopo awon eniyan
ni won maa wa woran orin re nitori ibadi re yato si orin ti n ko lenu.
Aworan re tuntun ni yii, mo kan ni ki n fi han yin ni. Bawo le se ri si?
0 comments:
Post a Comment