Smiley face

Se E Ti Gbo Orin Waka Tuntun Lati Enu Fathia Balogun?

Eyin tiatia nigboro aye, ise tiata oteyii tun koja ohun te e lero lokan o. Mo foju mi ribi ti Fathia ti n korin, eru bami. Muyiwa Ademola lo dari fiimu tuntun naa. Awada Broda Jelili ati Sanyeri tun je ohun kan ti ariwo re yoo tun gba igboro kankan nigba ti fiimu naa ba je. Igba die loku, won ti fe e se jina tan.



E ku oju lona!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment