Smiley face

Aremu Ti Pade Wale Lati Ilu Obama

Sebi mo so fun yin wi pe Kunle at Gabriel Afolayan wa ni ilu Seychelles. Saaju akoko yii ni Aremu Afolayan ti won jo je eje kan naa ti wa ni ilu Amerika. Sugbon bayii, omokunrin naa ti pada wale.

Bakan naa ni mo gbo wi pe Kunle ati Gabriel naa ti pada wale. Maa tun se ofintoto iwadii naa ati wi pe ibo ni won ba fidio orin Gabriel Afolayan to pe ni AWELEWA de.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment