Eye asa ti n fo loke ko ni won ri o, ASA omobirin olorin
ilu Nigeria ni awon kan foju kan ni ilu Paris to je olu ilu France pelu
aso funfun ati fila dudu. Omobirin naa tun de gogu pupa soju legbe kan
popona ilu Paris.
Igba kan ni awon kan fi esun kan
omobirin naa wi pe o maa n ni ibasepo obirin si obirin. Sugbon Asa so wi
pe iro ni oro naa, ati wi pe awon aye n binu eye asa oun lasan ni.
'Olayemi Oniroyin, so fun awon temi nigboro wi pe ilu France ni mo wa bayii, nibi mo ti n jaye bi Alaafin Oba Lamidi.'
0 comments:
Post a Comment