Smiley face

Ohun Ti Mercy Aigbe So Ati Ibi To Lo Lonii

Mercy Aigbe ji ni aro putuputu oni pelu erin nla ni enu re si awon ololufe re. Alaye re ko si po rara. O ni ninu ipokipo ti eda ba wa laye, ko ma se banuje rara ko si maa rerin idunnu lenu nigba gbogbo. Pelu adura ati iforiti ohun gbogbo yoo si pada si daradara.

Leyin eyi lo gbera lo sori eto ori telifisan kan gege bi alejo fun iforowanilenuwo.
O tun se alaye nipa alakorun re gege bi eroja oge tuntun ti won sese ba oun se, ati wi pe igba akoko ni yii ti oun yoo fi sorun jade.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment