Satide ola, 16th Aug, 2014 ni ami eye Yoruba Entertainment Award yoo maa waye.
Se
e ranti wi pe mo so fun yin wi pe Malaika ti fo lo si ilu Amerika, oun
ati awon olorin asa ibile Yoruba ni o maa da awon eniyan laraya nibi
ayeye naa.
Ankara lo se pataki ju, eni ti o ba ti wo ankara ko ni wole joko. To ba wole joko ko ni je semo.
E je ka pade nibe!
0 comments:
Post a Comment