Smiley face

Asa Ti Doosa Ajiki Nilu Paris

Awon Yoruba ni ile ni adiye funfun ko ti niyi sugbon to ba deta bi oba ni won se n ponle. Asha, omobirin olorin ilu Nigeria ti doosa ni ilu France pelu bi awon oniroyin ko se je ki omo naa gbadun mo.

Ohun to si maa n je larija ibeere won ni wi pe bawo ni omobirin naa se se alabapade aditu ogbon arojinle to kun inu orin re.

Won ni pupo ninu orin re ni eniyan le maa mo itunmo to ni nigba ti eniyan ba gbo leekan soso ayafi ti eniyan ba tun ronu sii daada.

Omo ilu Nigeria ni Bukola Elemide je, sugbon France ni won bi si ni ojo ketadinlogun osu kesan-an odun 1982.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment