Smiley face

'Inu Mi Dun Lati Wo Inu Ile Ebenezer Obey' - Irawo Osere Onitiata

Awon onise tiata ile Nigeria kan ni won lo ya ile agba olorin Juju, Ebenezer Obey lati ya fiimu.

Idunnu nla lo je si Desmond Elliot to je okan lara awon osere inu fiimu naa lati gbo wi pe ile Obey ni awon wa. Omokunrin naa ko le pa idunnu re mora rara pelu bo se foju kan Obey Commander.

'Alabukun ni mo je lati wo inu ile Obey. Inu mi dun bi sugar. Ayo mi si kun' Desmond

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment