Davido si n lo lati ilu kan bo si ilu mii ni ile Afirika nibi awon eniyan ti gba were skelewu bi eni wi pe won gbo orin ri.
Awon ololufe Davido ti jo skelewu tan ni ilu Nigeria, sugbon ni ilu Togo ti omokunrin olorin naa wa bayii, ijo skelewu sese bere ni.
E wo ero lagbo David omo Adeleke.
0 comments:
Post a Comment