Peter Okoye ti kede lori ero Twitter re wi pe banki kan mbe
ti won lu oun ni jibiti lati ojo to ti pe wa, sugbon ti asiri won ti tu
si oun lowo.
Omokunrin naa ti se ileri lati tu oruko banki naa saye ti won ko ba tete se atunse.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
8/03/2014 11:12:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment