Aare Goodluck Jonathan ti wo ilu Amerika fun ipade pataki ti yoo waye
lola ojo Aje [4-8-14]. Lara awon to wa ki Aare kaabo ni awon omo egbe
PDP ti won wa ni ilu Amerika.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment