Smiley face

E Joo, Se Won Ti Pin Fufu Aregbesola De Ile Yin?

Olori ajo INEC, Prof. Attahiru Jega ti je ko ye gbogbo ilu wi pe ko si ese nibi ka maa pin iresi tabi ebunkebun fun awon oludibo nitori ki won le teka.

Oro Jega ti fun awon oloselu lagbara lati tesiwaju ninu ise rere baba keresimesi ti won n se lati jere okan awon ara ilu.

Fufu Aregbe ni yii. Fufu naa dara lenu, kii run, bee lo si se e je efo riro ti won ti run eja si ninu. Ti eniyan ba fe pa ku, ti e fe jaye ju, e kan wa agolo miliki kan segbe pelu Motina tutu meji. Ori iya mi oooo! Ogun eje pelu energy to daju buruku. Chai!!!

E ku Sande!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

2 comments: