Smiley face

Aye Awon Asewo Igbalode Ilu Ghana

Oniroyin ayelukara kan ni ilu Ghana lo ti bere si i se akojopo iroyin nipa ise nabi (asewo) igbalode ni ile Afrika.

Ise iwadii re bere lati ile ijo kan ni ilu Accra nibi to ti salaye bi awon olomoge se maa n pate ara won kale bi igba eniyan ba ho osan kale fun mimu.

Orisii awon omoge yii, ipolowo oja ni won je fun ile ijo yii. Awon onibara kii gbe won lo, sugbon ko si ere ti won kii se fun awon eniyan ti won ba wa mu otin.

Ile ijo naa n san owo fun won ni, awon okunrin ti won n wa si ile ijo naa tun maa n fun won lowo latari bi awon omoge naa se maa n dun won ninu.

Kosi ara ti won ki fi awon omoge naa da, won maa n tika bo won nidi, fi enu fa oyan won, koda awon kan maa  n ba awon omoge naa sun nita gbangba.

Ile ijo yii kii se fun gbogbo eniyan rara, awon 'bigi boi' nikan ni won lo sibe lo se faaji nitori aladanla ni.

To ba ya, maa salaye fun yin bi e se de ile ijo naa ati iye owo ti e gbodo mu dani ti e fi ni anfaani lati je ajeku aye. Lol

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment