Toyin Aimakhu feran ko maa se afihan foto oun ati oko re
nigba gbogbo. Se kii se wi pe o n fi aworan naa la awon ti ko ti loko
loju?
Ko si ara ti oun ati oko re kii da to ba ku awon nikan ni yelu.
Leyin ti won ti fi enu ko ara won lenu tan, kini ohun to sele leyin igba naa?
0 comments:
Post a Comment