Funke Akindele ti pada sigboro pelu ipolowo ose OMO eleyii ti Jenifa je okan lara awon asoju ile ise ti n se ose naa jade.
Funke ko ni wa si adugbo yin lasan lati wa polowo, e o ma ni anfaan lati je awon ebun lorisiirisii pelu.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
8/21/2014 12:04:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment