Ilu Amerika ni Sola bi omo re tuntun si, ilu Amerika naa ni
won si ti so loruko. Obirin ni omo tuntun naa, awon ebi atore si rogba
yika lati se ajoyo omo tuntun ti Edua oke fi seke re.
Sebi e mo wi pe omo Iya Rainbow ni Sola fe?
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
8/21/2014 12:51:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment