Smiley face

Saidi Balogun Pade Fathia Balogun Nibi Ise Fiimu Tuntun

Sebi mo ti n je ki e ri gbo ni nnkan bi ojo meta seyin wi pe won ya fiimu tuntun Mercy Aigbe lo lowo eleyii to pe ni Life After Marriage.

Lara awon osere to pe senu ise re tuntun naa ni Saidi Balogun ati Fathia Balogun eni to ti yi oruko re pada si Fathia Johnson bayii.

Pelu akole fiimu tuntun yii, ati bi Mercy Aigbe se pe Saidi ati Fathia papo yii, se ki i se wi pe o fe fi won ta fiimu re?

Sebi tori ka le jere naa la fi n se bisineesi. Eniwee, emi maa dake na.

Bi o ba se n lo, maa tun ma ja yin si.

Sugbon ki n to lo, nje e ti gba kaadi idibo lailai ti yin?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment