To ba je Babalawo lo se fun Innocent Idibia, Babalawo oun ti bo saye. To ba si je wi pe onisegun lo ba gunse ori ire, a je wi pe asiko ti to ti osanyin babalawo re yoo maa gun mesi oloye.
E o so wi pe ki lo fa sitori repete?
Awo orin tuntun Tuface Idibia, THE ASCENSION to je eleekefa ti o se jade ti wa ni akaba kejila (12th) bayii ninu awon orin ti n taju lagbaye. Bi won se ra lori ero ayelukara ni won ra loja lori igba witiwiti.
Laifi oro si abe ahon so, ipo agba ni Tuface wa laaarin awon olorin ile adulawo. Eyi si je ara nnkan to mu yii oruko re pada si Tu-Baba.
Odun 1975 ni won bi Innocent Ujah Idibia ni ilu Jos to wa ni Ipinle Plateau. Akosile si fi ye wa wi pe odun ti MTV Africa wo ile adulawo, orin African Queen ti 2Baba ni won koko fi sori afefe. Yato si ebun orin ati ohun didun, Tubaba ni a ba tun maa pe ni Papa Tosibe fun awon 'ise rere' re ni igboro aye ni awon akoko kan seyin.
0 comments:
Post a Comment