Smiley face

Won Ti Pa Sule Okunrin Meta Soju Ogun

Ninu iwe itan aroko OWO EJE ti Oloogbe Kola Akinlade ko, atenuje lo pa Sule Igbira. Sugbon ninu ijakadi nla to waye laaarin iko Boko Haram ati awon omo ologun Nigeria to waye lopin ose to koja ni Ipinle Borno, ise ilu ati jije olododo si orileede eni lo pa Captain Sule Benjamin loju ija. 


Iku akoni yii waye leyin osu mejo to se igbeyawo alarinrin eleyii to je ibere igbe aye otun.

"Captain Sule was killed in a battle launched by Boko Haram fighters against our troops between Saturday and Sunday.''

I received the news with utmost shock. He was killed between Saturday and Sunday, but we only got the information today [Ojo Aje]." Ore Sule to wa ni Bareke awon omo ologun ti Ipinle Cross River.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: