Smiley face

Oyinlola Ti Pada Sinu Egbe APC

Gomina Ipinle Osun nigba kan ri, Omo'ba Olagunsoye Oyinlola ti gba bayii lati darapo mo egbe APC. Gege bi iroyin ti a gbo, o ni yii [5-8-14]  ni won yoo gba agba oloselu naa wole pelu ijo ati ilu ni ilu Oshogbo Oroki.

Igbese tuntun yii ti bere si ni da aibale okan sile ninu egbe PDP ti Ipinle naa. Nitori ti igbin ba fa, ikarahun di dandan ko tele. Ohun to daju ni wi pe aimoye oloselu ti won je olooto si Oyinlola ti won wa ninu PDP ni won o jo maa ju igbale soke losan oni yii ni gbagede, loju gbogbo omo Osun pata.

"The first elected governor, Alhaji Isiaka Adeleke, is with us; the second governor, Baba (Bisi) Akande is with us. The third governor Omo'ba (Prince), is also with us. I can say this but they cannot say it.'' Ogbeni Aregbesola

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment