Basket Mouth, okan lara awon onise alawada ile Nigeria ti so fun awon oniroyin kan wi pe Sunday Omobolanle ti gbogbo eniyan mo si aluwe je okan pataki lara awon akoni ti won bere ise awada sise ni ile Nigeria saaju ki awon to de.
Omokunrin onirawo meje ninu ise aderinposonu naa se apeere Aluwe gege bi oosa ti awon eniyan gbodo maa ponle nigba gbogbo.
Sebi ti onirefin ko ba fingba mo, eyi to ti fin ko le pare ninu itan lailai.
0 comments:
Post a Comment