Ti a ba n so nipa ise olootu orin kiko ni ile Nigeria ati Ile Adulawo lapapo, oga ni kaun lawujo okuta, oga ni Michael Collins ti gbogbo eniyan mo si Don Jazzy. Aworan baba ati iya maanu naa ni yii.
Oke okun ni iya re n gbe sugbon baba re ko duro soju kan soso.
0 comments:
Post a Comment