Awon olopa Ipinle Edo ti mu omokunrin eni odun mokandinlogun (19) kan ni agbegbe Iguosa to wa ni Ijoba Ibile Ila-Oorun Ariwa Ovia pelu esun wi pe o ba aja lajosepo.
Omokunrin ti won pe oruko re ni Osagiator ni awon eniyan ka mo inu ile akopati kan ni agbegbe naa nibi to ti n ti nnkan omokunrin re bo inu idi aja.
Ninu oro omokunrin yii, o ni oun ko le so ohun to ti oun sibi iru isele yii. Pelu omije ni omo naa fi n so tenu re fun awon olopa ni akoko ti n soro yii.
Awon ara ilu ti pa aja naa bayii, awon olopa si ti mu Osagiator lo.
0 comments:
Post a Comment