Smiley face

Nje E Ti Gbo Wi Pe Ikebe Awon Omoge Anambra N Fa Ebola?

E ku asiko yii nibi gbogbo tie ti n ka iroyin Olayemi Oniroyin Agbaye. Iroyin ti o common leyii, eleyii to n se kilokilo wi pe ki e sora fun ikebe awon omoge Anambra.


Iwadii tuntun awon dokita lo fi eleyii ye wa. Won ni awon eroja kan wa lara awon eroja inu ikebe awon omoge Anambra eleyii to le fa arun Ebola ti n seku pani ni kiakia.
Gege bi onimo isegun oyinbo, Dokita Kowope Irunmulowo alias Baba Alabere Sokisoki se so, o ni awon eniyan ni lati sora gidigidi fun orisii ikebe to le sakoba arun ebola eleyii ti ikebe awon omoge Anambra je pataki ninu awon idi pataki naa.

'Orisii ona meta ni e le gba ko Ebola nipa ibadi awon omoge Anambra. E le ko Ebola ti e ba fowo kan ikebe Anambra tabi ti e ba wo lawo ju. Ti eniyan ba fe ku ni kiakika, leyin to foju kan ikebe Anambra, to fowo te idi naa lati mo bo se ri lowo, to tun wa de isale eko to gbabe jade si tinubu. Bi eni naa ba se n jade ni tinubu bayii, obituary re ni won o kede lori redio,' Baba Alabere sokisoki lo so bee.

Idi ni yii ti a fi n ro awon eniyan wi pe ki won sora fun ikebe. Paapa ju lo, Ikebe awon omoge Anambra.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment