Smiley face

[Foto] 'Aye Mi Ni Mo N Je' Dayo Amusa

Dayo Amusa si wa ni Ilu Oba nibi to ti gbe n gbadun bi era to ko sinu sugar. 

Olorun nikan lo mo iru ipara ti omobirin naa n lo eleyii to mu ara re tutu minijojo bi ara omo tuntun. Se ounje ni abi afefe ilu Biritiko?



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment