Awon ololufe Funmi ni ilu London ni won da ariya kale fun un lati fi ba yo ayo ojo ibi re to ba laye.
Bi o tile je wi pe osu to koja ni Funmi le lodun, sugbon awon Yoruba bo, won ni ko si igba ta daso taa rile fi wo.
Inu Funmi dun, eyin naa yoo si ri apeere pelu bi o se mura si ijo naa ni gidi.
0 comments:
Post a Comment