Awon eniyan merin ninu awon eniyan ti arun Ebola mu ti yege leyin itoju ti won ko bo won loju paali.
Awon
eniyan yii ni awon osise onisegun oyinbo ti won toju omo Liberia to
koko ko arun naa wole nigba ti okan ninu won je alaisan to wa ni osibitu
ni akoko naa.
Atejade tuntun to te wa lowo ni yii
"The Minister of Health Prof. Onyebuchi Chukwu has announced that four additional confirmed cases of Ebola Virus Disease who have been managed successfully and are now disease free have been discharged home today."They include two male medical doctors and one female nurse. The three participated in the treatment of the index case while the fourth person was a female patient at the time the index case was on admission."This brings to five the total number of patients diagnosed with Ebola Virus Disease who have now been discharged from hospital."
Olorun seun oooo
ReplyDelete