Leyin ipolowo ose OMO ti Funke Akindele ti n polowo kiri igboro, gbajumo osere naa ti pada senu ise tiata re lakotun. E le ka iroyin ipolowo ose OMO naa [NIBI]
Bi
o tile je wi pe a ko ti mo akole fiimu tuntun naa, sugbon ohun to daju
ni wi pe 'pami-n-ku-sori-benbe-soko' ni ipa ti Jenifa ko ninu fiimu
tuntun ti won ya lowo naa.
0 comments:
Post a Comment