WeirdMC wa lara awon olorin ti Ogbeni Rauf Aregbesola ko wo Ipinle Osun ni akoko ipolongo eto idibo gomina to waye laipe yii.
Bi
o tile je wi pe o ti to ojo meta bayii ti awon eniyan ti ri orin tuntun
WeirdMC nigboro aye, sugbon o dabi eni wi pe iya Ijebu setan ti o pada
sori gangan.
Nikete ti Weird MC pari ipolongo Ogbeni
Rauf Aregbesola, eni to na Iyiola Omisore bi ole to ko sowo soja ninu
eto idibo gomina tuntun ipinle naa lo ti fo lo si ilu South Africa lati
lo ya fidio orin re tuntun to se.
Eni a n gbe iyawo bo wa ba, kii gbe ori iganna woran. E ku oju lona!
0 comments:
Post a Comment