Gbogbo igba ti mo ba fi oju mi kan Kanu Nwankwo to je agbaboolu ile Nigeria nigba kan, iranti bo se dana sun egbe agbaboolu Brazil ni ilu Amerika nibi idije Olympic to waye ni Atlanta lodun 1996 lo maa n so si mi lokan. Odun 2004 ni Kanu se igbeyawo alarinrin pelu Amarachi. Edumare si ti fi omo meta si aarin won. Inu ayo ati idunnu nla ni awon mejeeji si n gbe papo lati igba naa di oni. E je ka lo aworan idile Kanu pelu orekelewa aya re.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment