Eniyan to ba onire yo, dandan ni ko ri ire gbamu. Iroyin ti kan wa wi pe won ti bimo ni idile Yinka Ayefele (MON), okunrin lantilanti si ni omo naa. Gbogbo wa pata la ba olomo yo lonii. Edumare a ba wa da omo naa si. Ko diru, ko digba. Congratulations!
Orin King Rokan to pe ni Omo Tuntun ni a maa fi ki Yinka Ayefele ku orire. E gbo orin naa [NIBI]
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment