Awon Yoruba ni ti ewe ba pe lara ose, ewe a yira pada dose.
Sasa eniyan lo le gba wi pe omoTogo ni Liz Da Silva, Yoruba enu re da
saka o si mo ise re doju amin. Ilu Eko ni won bi si, o si ti salaye ni
awon igba kan wi pe Iyabo Ojo lo ran oun lowo lati wonu ise Tiata ni
odun 2004.
Mi o sadeede gbe Liz Da Silva wa soju iworan
yin lasan, o ni ise akanse kan ti won fi ran mi ni. Ohun tuntun kan mbo
lati owo irawo osere naa.
Nje kini ohun tuntun naa?
E ku oju lona!
0 comments:
Post a Comment