Kala Kaiwi ni won ti fi
ami eye Guinness World Records dalola pelu ara to fi eti re da. Won ni
oun ni eni akoko ti yoo so eti re di titobi olobiripo to fe ju lo lai se
ise abe.
Ise
tatto yiya ni okunrin yii n se ni ilu Amerika. Hawaii lo ti n tewo gba
dollar leyin to ba ya awon eniyan lara tan. Kosi si iru tattoo ti oun
gan-an ko ni lara; sebi eni ti o daso fun ni torun re laa ko wo. Koda,
okunrin naa tattoo eyinju re kan.
Ojo
ti mo ba wo ilu Amerika, ma wa okunrin yii kan ko se iru eti nla bi
eleyii fun emi naa ki n maa fi swagger kiri igboro. Emi fun rami, emi
omo jayejaye to donjasi.
0 comments:
Post a Comment