
Se e ranti wi pe mo ti salaye fun yin tele wi pe Kunle Afolayan ti wo ilu Seychelles pelu alaye mi nipa ilu naa.
Tuntun ni wi pe won n ya fidio orin tuntun Gabriel eleyii to pe ni AWELEWA lowo bayii ni ilu naa. Ti eyin ko ba ka iroyin naa tele, e le ka [NIBI]
0 comments:
Post a Comment