Oba Ikorodu, Ayangburen of Ikorodu, Oba Dr. Salaudeen
Oyefusi (Oguntade II) ti waja ni ale ana ni Ilu London nibi to ti n gba
itoju.
A ko ti le so iru iku wo pato lo mu oba alaye
yii lo nitori ko ti si iroyin lori koko aisan to gbe kabiesi lo si
United Kingdom lati Nigeria.
Eni odun metalelogorin [83] ni baba ki won to dagbere fun aye. Ki Oluwa ba wa te won si afefe rere. Amin.
0 comments:
Post a Comment