Okan ninu awon alaye itumo DORO gege bi Don Jazzy se so ninu orin eleyii ti igbimo awon olorin Mavin ko ni wi pe, Doro je eni ti n fi fun ni-'Doro na Giver,.
Igbese naa ni Don Baba to je Oga Nla Mavin n tele pelu bo se fun Tiwa Savage ni oko nla lojo to se igbeyawo alarinrin.
Dr Sid naa se igbeyawo laipe yii, oun naa si ti gba oko nla tuntun Toyota Prado SUV 2014 tie naa lati owo Don Jazzy.
0 comments:
Post a Comment