Smiley face

Oge Ini Edo Ti Le Won Sare

Awon Yoruba ni ti omo eni ba dara ka wi. Omo eni ko si ni sedi bebere ka wa fi ileke sidi omo elomii lailai (nigba ti won o sepe fun'yan). Ini Edo rewa, ewa si peleke. 



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment