Ise tiata kii se ise enikan soso, ajumose ni. Aimoye awon
eniyan ni won si n sise takuntakun leyin itage eleyii ti enikeni ko mo
nipa won.
Lekookan, maa ma se afihan awon eniyan ti won
se ise opolo to gbamuse leyin itage ati awon ise won gbogbo lati se
koriya fun won.
Sebi awon Yoruba lonii enikan kii je awade, opo eniyan ni i je janmoo.
0 comments:
Post a Comment