Awon omo ibeji Okoye, P-Square ti wo ilu Cameroon lati maa pidan ohun ori ran waye wa se.
Awon
naa fese kan ya nile awon omo alainiya bi Davido se se ni Abidjan lati
fun awon omo naa lebun to joju nikete ti awon oniroyin fi oro wa won
lenu wo tan nipa orisii orin ti won gbe wo ilu Cameroon.
Peter ti leri, Paul to je Kehinde re naa ti soro, won ni asiko yii ni ilu Cameroon o gba wi pe eran to yi ni won pe ni namo.
0 comments:
Post a Comment