Smiley face

'Aisan Ti N Semi Koja Owo Ati Okiki' - 50Cent

50Cent ninu baalu adani tie
'Eniyan le fe lowo ko lowo tabua .
Eniyan le wa okiki ko gbayi repete.
Sugbon aisan ti n semi koja owo ati okiki.
Arun ti n semi wa ninu erogba mi fun ojo ola
Eyin temi, e maa gbadura fun mi.' -50Cent


Bi owe bi owe ni 50Cent n soro ni aaro yii. Awon oro re si gba arojinle gidi. O da bi eni wi pe awon nnkankan wa ti omokunrn olorin naa n le ninu igbesi aye re eleyii ti owo ati okiki to ni ko le fun-un eleyii to je edun okan nla gidi fun-un. Adura wa ni wi pe ki Olorun ba wa tu ninu.
 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment