Smiley face

Omo Odun Mokandilogun Ba Adiye Sun Ni Ilu Akure

Gege bi okan lara ewi Olanrewaju Adepoju, akewi ni eni aye ba da yerepe adanwo si lagbada ti onitoun ba ri omo Awo ko ni pegan. E yii tunmo si wi pe ohun ti won pe ni Aye Akamara wa.

Lori akawe yii ni maa ti ya si isele to sele ni ilu Akure nibi ti omokunrin eni odun mokandinlogun (19) kan to je omo ikose owo ti a fi oruko bo lasiri ti ba adiye lajosepo titi adiye naa fi ku. Gege bi iroyin taa gbo, won ni omo naa ti ba ewure sun ri eleyii si wa lara nnkan ti awon ebi re fi pati lati ojo pipe seyin.
E gbo ohun ti omo naa so:

'Mo ti n sun lo ki emi kan to ba mi soro wi pe ki n dide, ki n maa lo seyin ile nibi ti adiye wa. Mi o mo ohun ti mo n se nigbogbo akoko yii, mo kan saa sakiye wi pe mo ti ba adiye ni ajosepo ni. Oro igbe aye mi ko ye mi mo rara.'
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment