Bi won se n sere naa ni yii. Enikan ni o bere pelu dida
omi tutu sara re niwaju kamera. Leyin eyi ni yoo wa daruko awon eniyan
meji ninu awon ore re lati fi pe won nija lati se bakan naa.
Enikeni ti won ba ti daruko re gbodo da omi tutu le ara re lori laaarin wakati merinlelogun ti eni akoko ti se bee.
Ibere
pepe ere yii waye lati fi seto ikowojo fun awon eniyan to ni in lo
iranlowo. Sugbon bayii, o ti di ere idaraya ti gbogbo awon amuludun
agbaye tewo gba bi igba otin.
0 comments:
Post a Comment