Smiley face

'Ti E Ba Ri Adebayo Salami, E Ba Mi Ki Daada' Desmond Elliot

'Kii se gbogbo igba ni mo maa n pade awon agba osere fiimu Yoruba nitori ise kii pawapo lopolopo igba. Sugbon e kookan ti mo ba ri won, mo maa n se aponle won daada. Ti e ba ri Adebayo Salami, e ba mi kii daada. Baba ni father' -Desmond Elliot


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment