Funke Akindele bere ipolowo ose OMO lonii eleyii to n se
lati ojule de ojule. Ni aro oni [2-8-14], ori redio Cool FM lo ti bere
ipolowo oja naa ko to kori si agbegbe Ogba to wa ni Ilu Eko.
Iyalenu
nla lo je fun awon olugbe agbegbe yii nigba ti Jenifa kan ilekun won.
Awon kan kigbe bi won se ri i, awon kan sebi ala ni awon nla, nigba ti
awon kan fo mo o lorun pelu erin ati idunnu.
O seese ko je wi pe adugbo ti yin ni Sulia Ayetoro mbo lola.
E ku oju lona!
0 comments:
Post a Comment