Juliet Ibrahim lo menu ba ilu Nigeria lori ero Twitter re
gege okan lara awon ilu ti arun Ebola n ba finra. Oro to so ni yii, ni
awon omo Naija ba tuto soke ti won si foju gbaa.
Won ni radarada lo n so lenu ati wi pe ilu tie gan-angan to je ilu Awon Aganyi loni arun naa kii se Nigeria rara.
0 comments:
Post a Comment