50 Cent, ogbologbo onkorin takasufe ilu Amerika ti kede wi
pe orin oun tuntun ti wa lori ina. O si salaye orin tuntun naa gege bi
ohun ti itan o maa soro ba ni nnkan bi egberun odun leyin ti orin naa ti
jade.
Ko ti i so igba ti orin naa yoo jade, sugbon o daju wi pe ko ni pe rara.
'Orin Mi Tuntun Maa Da Ile Aye Laamu' 50Cent lo so bee.
Awon
onwoye nipa amuludun so wi pe o seese ki orin tuntun 50 Cent mi igboro
titi looto gege bi orin re kan to ju si igboro lojo keje osu kinni odun
2003, ti won pe akole re ni IN DA CLUB.
Orin yii nikan
soso ta bi milionu meji, igba meji naa ni orin yii fara han ninu ami eye
Grammy ti eleekerindinlaadota to waye ni Ilu America.
0 comments:
Post a Comment