Ojo oni dun, agbaoje omobirin olorin ilu Amerika, Nicki Minaj rode ariya, gbogbo eniyan niwon si ni aso omo naa gbayii pupo.
Aso ti n dan boroboro naa bo gbogbo ara Nicki yato si awon aso esubeleke ti opolopo awon ololufe re mo pelu re.
Ko ba si dara to ba le tesiwa ju bayii.
0 comments:
Post a Comment