Smiley face

E Wa Wo Swagger Afeez Abiodun Ninu Sinima Tuntun To Fakiki

Ise tiata dabi ise orin ni. Bi olorin se gbodo ko tuntun ko le wa lori igba bee naa ni onise opolo gbodo maa gbe ara tuntun yoo ni gbogbo igba.

Afeez Abiodun ti gbogbo eniyan mo si Sarki Olopolo ti bere ise tuntun eleyii to se ara oto gedegede.

Swagger lasan ni mo ri, alaye inu m bo laipe.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment