Sebi Aremu Afolayan lo lo ge irun ori re lowo onigbajamo, igba ti won gerun re tan lo beere lowo awon ololufe re wi pe bawo ni ori oun se ri.
Broda Kasali lati Oju Elegba ba fun lesi pada. O ni, "Mr Aremu, ori yin ri kedere bi ori maalu".
Aremu naa ba pada wa 'fucki yu' broda Kasali ni score ba di 1-1.
E ku faaji opin ose!
0 comments:
Post a Comment